Full Lyrics
INTRO
Ara ẹ wá bá wa yọ,
Ara ẹ wá bá wa yọ n'ile o l'ọrun.
Ara ẹ wá bá wa yọ n'ile o l'ọrun.
Ayọ kúnnú ẹkún wa o n'ile o l'ọrun.
VERSE 1
A dupẹ Baba fun oloore ni o.
A mọ're Baba a wa dupẹ o.
Káre Baba wa, a sá di o.
Eledumare dakun gbọpe wa o.
VERSE 2
Awa yoo yin Oluwa ẹni to gbà wá,
A tẹriba a wolẹ n'iwaju rẹ.
Káre Baba wa, a sá di o.
Olugbala dakun gbọpe wa o.
VERSE 3
Ko s'ẹni mimọ a fi'wọ nikan.
Iwọ l'Oluwa o l'ogo julọ.
Káre Baba wa, a gbe o ga.
Olumọran dakun gbọpe wa o.
Baba Olumọran dakun gbọpe wa o.