Ará ẹ Jẹ́ Kálọ Rúbọ by Albert Gomez & Macartm Odeke — Lyrics

Albert Gomez & Macartm Odeke Yoruba Offertory Hymns Folk songs Solfa notation

Full Lyrics

VERSE 1 Ará ẹ jẹ kálọ rúbọ o, s'Ọlọrun Ọba oke, t'o da gbogbo wa. Ará ẹ gbogbo wa. Tirẹ lawa jẹ o, tirẹ lawa jẹ, lọwọ Rẹ lawa wa o. Gbogbo ohun ti a ni la fi rúbọ wa. VERSE 2 Jesu lẹni ti a ru lẹbọ o, s'Ọlọrun Ọba oke, t'ọwọ gb'ẹbọ wa. Jesu o gb'ẹbọ wa. Dariji wa, Baba, dariji wa, dakun, ṣiju aanu wo wa. Tẹwọ gb'ẹbọ ti a ru o, Baba wa. VERSE 3 Ẹ wa ẹ jẹ ka sin l'ọrun o, s'Ọlọrun Ọba oke, ti a gb'oju le. Ẹ wa ẹ gb'oju le. Iwọ lajiki o, Iwọ la jiki, ṣebi 'wọ lajiyin o. Titi lọ lawa o maa yin Ọ, Baba. VERSE 4 Ará ẹ jẹ ka yin l'ọrun o, s'Ọlọrun Ọba oke, t'o fi wa s'aye. Ará ẹ wa s'aye. Iwọ lan fẹ o, Iwọ la n fẹ, ṣebi 'wọ lawa mọ o. Laye wa k'awa o maa yin Ọ, Baba.

Download the sheet music

Ará ẹ Jẹ́ Kálọ Rúbọ

Ará ẹ Jẹ́ Kálọ Rúbọ

By Albert Gomez & Macartm...
Solfa
Yoruba
1 page
0 Downloads
Offertory Hymns Folk songs
0 0

More lyrics you may want