Gloria - Yoruba (Ara E Gbe E Ga) by Jude Nnam — Lyrics

Jude Nnam Yoruba Gloria Hymns Solfa notation

Full Lyrics

[INTRO] Ogo ni f'Ọlọrun loke ọrun Alaafia si ni laya f'awọn ẹda Ọlọrun rere [CHOIR] Baba wa a gbe Ọ ga A fiyin a t'ọla fun Ọ [REFRAIN] Ogo yẹ f'Ọlọrun wa Ogo yẹ f'Ọlọrun wa Ara ẹ gbe e ga Ọpẹ yẹ f'Ọlọrun Ọpẹ yẹ f'Ọlọrun Iyin yẹ f'Ọlọrun Ogo yẹ f'Ọlọrun wa Ogo yẹ f'Ọlọrun wa Ogo yẹ f'Ọlọrun wa Amin. [VERSE 1] Oluwa Ọlọrun wa Ọdọ Aguntan Ọlọrun Iwọ to nko ẹsẹ aye lọ Saanu fun wa gbọ ti wa [VERSE 2] Iwọ nikan lẹni mimọ Oluwa to ga julọ Jesu Ọmọ Baba Ninu isọkan Ẹmi mimọ

Download the sheet music

Gloria - Yoruba (Ara E Gbe E Ga)

Gloria - Yoruba (Ara E Gbe E Ga)

By Jude Nnam
Solfa
Yoruba
3 pages
32 Downloads
Gloria Hymns
0 0

More lyrics you may want