GLORIA - YORUBA 'Chris' by Jude Nnam — Lyrics

Jude Nnam Yoruba Gloria Hymns Solfa notation

Full Lyrics

INTRO Ogo ni f'Ọlọrun loke ọrun, Alaafia si ni laya f'awọn ẹda oninu rere. VERSE 1 Baba wa a gbe Ọ ga Afiyin a l'ọla fun Ọ Ogo yẹ f'Ọlọrun wa Ogo yẹ f'Ọlọrun wa CHORUS Ara ẹ gbe e ga Ọpẹ yẹ f'Ọlọrun Iyin yẹ f'Ọlọrun Iyin yẹ f'Ọlọrun Ogo yẹ f'Ọlọrun wa Ogo yẹ f'Ọlọrun wa Ogo yẹ f'Ọlọrun wa Amin. VERSE 2 Oluwa Ọlọrun wa Ọdọ Aguntan Ọlọrun Iwọ to nko ẹsẹ aye lọ Saanu fun wa gbọ ti wa VERSE 3 Iwọ nikan l'ẹni mimọ Oluwa to ga julọ Jesu Ọmọ Baba Ninu isọkan Ẹmi mimọ

Download the sheet music

GLORIA - YORUBA 'Chris'

GLORIA - YORUBA 'Chris'

By Jude Nnam
Solfa
Yoruba
3 pages
13 Downloads
Gloria Hymns
0 0

More lyrics you may want