Full Lyrics
Iyin at' ope ni fun O O Baba
Oba Iye a n yin O Olorun wa
Oba mi iwo O Oba O Oba O O
Alade ogo e se o
Olorun iye gbogbo wa dakun gb'ope wa
Alade Ogo
Adupe fun oun gbogbo ti e ti se
Adupe fun oun gbogbo ti e ti se Olupe
A n yin o Oba mimo O Olorun gbogbo aye
Baba dakun gb'ope wa Alade Ogo
Alade ogo gb'ope wa
kan oba to n se'gun re se fun wa
Alade ogo dakun gb'ope wa
Alade Ogo gb'ope wa
A a gb'ope O Baba jowo gb'ope wa
Baba A wi ma ye'hun Baba O
Baba A dupe O Baba e se o
Baba Iwo lo pe ye Baba e se o
Baba e se o Baba e se o
Baba e se o Baba a A
mimo Olorun gbala Baba ato bi ju lo Adupe
pe fun iye re Oba mimo A wi ma ye'hun Baba
Olupe se Ope ye Oba O ye ka ye O Oba nla nla nla
nla Oba nla nla Oba nla nla Oba nla nla Oba nla nla Oba nla nla Oba nla nla Oba nla
ye Oba igbala nla Oba nla nla Oba nla nla Oba nla nla Oba nla nla Oba nla nla Oba nla
Oba nla nla nla Oba nla nla Oba nla nla Oba nla nla Oba nla nla Oba nla nla Oba nla
Baba jowo gb'ope wa
Ope ye O Baba Ope ye O Baba Ope ye O
Baba Ope ye O Baba Ope ye O Baba Ope ye O
Baba Ope ye O Baba Olodumare Oba ogo O
Baba Ope ye O Baba A dupe O Baba A dupe O
Baba Alade Ogo
Alade ogo Edumare dakun jowo O gb'ope wa