Full Lyrics
[ALADE OGO GB'OPE WA]
Iyin at'ọpẹ ni fun Ọ Baba, Ọba yẹ a'n yin Ọ
Olu ọrun Ọba mimọ Ọ, Ọpẹ yẹ Ọ
Alade ogo, gb'ọpẹ wa, Ọlọrun l'ye Ọ gb'ọpẹ wa
Alade ogo, Adupe fun ohun gbogbo, ti ẹ ti ṣe, Olu pẹ sa gba iyin
a'nyin Ọ, Ọba mimọ Ọ, Ọlọrun gbogbo aye, Baba dakun
kun gb'ọpẹ wa, Alade ogo gb'ọpẹ, gb'ọpẹ wa, Alade ogo gb'ọpẹ
gb'ọpẹ wa, Alade ogo gb'ọpẹ, Olumọrọ kan Ọba to n ṣeun rere fun wa
Alagbada ina, Ọba l'yẹ Ọ, gb'ọpẹ wa, Ọba rere
Awi mayehun, gb'ọpẹ wa, Alade ogo gb'ọpẹ
gb'ọpẹ wa, Alade ogo gb'ọpẹ, gb'ọpẹ wa, A gb'ọpẹ wa
Baba gb'ọpẹ wa, Baba gb'ọpẹ wa, Baba gb'ọpẹ wa
Baba gb'ọpẹ wa, Baba gb'ọpẹ wa, Baba ẹṣe o
Baba iwọ lo pẹ yẹ, Baba ẹṣe o, Baba fun gbogbo ti ẹ ṣe, Baba ẹṣe o
Baba Awi mayehun, Baba ẹṣe o, Baba A mimọ Ọ
ni d'Olugbala Baba atobiju, lo A dupẹ fun iye rẹ, Ọba mimọ Awi mayehun Baba
Olu pẹ ṣe Ọ pẹ yẹ, Ọba ayeraye Ọ Ọba nla
La Ọba nla, Kabiyesi Ọ ọwọ lo pẹ yẹ, Iwọ l'ọba l'yẹ Ọba l'gba la
La Ọba nla, Iba ni fun ẹ o Baba, Ọba nla nla nla nla
ni Olugbala Baba atobiju, lo A dupẹ fun iye rẹ, Ọba mimọ Awi mayehun Baba
Olu pẹ ṣe Ọ pẹ yẹ, Baba jọwọ gb'ọpẹ wa, Baba Ọ pẹ yẹ o Ọ Baba
Baba Ọ pẹ yẹ o Ọ, Baba Olodumare Ọba Ogo Ọ pẹ yẹ o Ọ Baba
Baba Ọ pẹ yẹ o Ọ, Baba A dupẹ, Baba Ọ pẹ yẹ o Ọ Baba
Alade ogo, Alade ogo
Edumare dakun gba wa o, gb'ọpẹ wa
[ANURIRIM ONU]
Añụrịrị m, Añụrịrị m ọñụ mgbe m nụrụ ka ha n'ekwu
Añụrịrị m ọñụ mgbe m nụrụ ka ha n'ekwu ka anyị jee n'ụlọ Dinwenu
Jerusalem, Ugbu a ụkwụ anyị guzoro n'ọnụzọ gị
Ewuru Jerusalem ka nnukwu obodo ewokọtara ọnụ me ka o si eike di n'ebe ahụ
K'agbụrụ nile ga ezukọ, agbụrụ nke Dinwenu
N'ihi na nke a bụ iwu Israel, ị to aha Dinwenu ebea
N'ebe ahụ e doziri oche eze, ikpe nke ezi n'ụlọ David