Full Lyrics
[CHORUS]
Akara ti ọrun, ti a fi fun wa, Ounjẹ mimọ!
Akara ti ọrun, ti a fi fun wa, Ninu ounjẹ
mimọ yi, a ri're ti wa, Ara Kristi, ara Kristi,
imọlẹ ayeraye, ẹjẹ Rẹ iyebiye,
imọlẹ ayeraye, imọlẹ ayeraye.
[VERSE 1]
Èjẹ Kristi, O ti wẹ ẹṣẹ wa kuro,
ninu anu Rẹ a di pipe;
Olurapada wa, ọba ayeraye,
a ṣe tan lati gba ọ, oninu rere.
[VERSE 2]
Agbara n bẹ, Ounjẹ aramada ti a fun ni bii
majẹmu, O jẹ ohun ijilẹ ti o tobi ju lọ,
Agbara n bẹ ninu Yukaristia mimọ,
Agbara majẹmu lo'n bẹ ninu Yukaristia Mimọ,
Agbara majẹmu laarin ọrun ati aiye
lo wa ninu Yukaristia Mimọ.