Full Lyrics
INTRO
Adupe fun o un ti e se fun wa oo
Ore re ninu aye wa o ma kpo
Olufe se ese Olugbala adupe o
REFRAIN
Gbo'pe wa Baba
Gbo'pe wa o yin a to go lo ye o o Baba, fun ore re oo
Awa la ti dupe iyanu re lori wa,
Ese Baba adupe o Oba wa ese Oba wa
VERSE 1
Gbogbo iye ti a ni laye
Baba lati odo re lo ti wa
Oba mi, melo Oba Oke,
Olu Orun oo Olubukun
Olutoju a gbe o ga.
VERSE 2 (TENOR SOLO)
Awa omo araye awa dupe ore ana
Adupe ore oni, a tun dupe ore ola
Gbo'pe Baba wa, gbo'pe Omo,
Gbo'pe oo Emi Mimo, wa gbo'pe Baba
Alade Ogo adupe ore re
VERSE 3 (CANTOR & OSTINATO)
Kabiyesi Baba, Eledumare o
Oba awa dupe ore,
Olufese, Oba Pipe awimayehun o
Oba awa dupe ore
Olugbala, Oba aye atofarati o
Oba awa dupe ore
Awa dupe ore