Full Lyrics
Oṣe Jesu, oṣe o!
Oṣe Oluwa fun ohun to ṣe fun wa.
Jesu oṣe. Oluwa adúpẹ́ o!
Oṣe, oṣe, oṣe o, Baba mi o!
Adúpẹ́ Jesu, Baba mi o adúpẹ́ o!
Jesu oṣe o, adúpẹ́ o, Baba!
Oṣeun Baba, Oṣeun Baba.
Inú wa dùn. Oṣeun o.
Ti o jẹ ki a wa laiye o.
Inú wa dùn lọ́pọ̀ lọ́pọ̀. Oṣeun.
Ohun gbogbo ti a ni, gbogbo ti a ni.
Oluwa ti ọwọ rẹ wa.
Jesu, Oluwa, Oluwa, Oluwa bawo lo ṣe tobi to.
Jesu, Oluwa, Oluwa, Oluwa bawo lo ṣe tobi to.
Oúnjẹ ti anjẹ. Uh! Baba mi o, ẹyin lo fun wa.
Jesu, Oluwa, Oluwa, Oluwa bawo lo ṣe tobi to.
Jesu, Oluwa, Oluwa, Oluwa bawo lo ṣe tobi to.