Full Lyrics
INTRO
O ṣe Oluwa Jesu
O ṣe o Jesu a dupẹ o Baba
O ṣe o Jesu a dupẹ o
CHORUS
O ṣe Oluwa fun ohun to ṣe fun wa
O ṣe Oluwa fun ohun to ṣe fun wa
Ṣe Oluwa Jesu, o ṣe a dupẹ Baba
Ṣe Oluwa Jesu, o ṣe a dupẹ Baba
VERSE 1
O ṣe l'ohun gbogbo inu wa dun l'ọpọlọpọ
To jẹ k'awa l'aye inu wa dun l'ọpọlọpọ
Ohun gbogbo ti a ni ti ọwọ rẹ wa Jesu Oluwa
Bawo ni a ṣe tobi to
VERSE 2
Ounjẹ ti a n jẹ
Aṣọ ti a n wọ l'ara wa
VERSE 3
O ṣe fun alafia
Ati ayọ to fun wa
VERSE 4
O ṣe fun ibukun
Ati ifẹ o ni si wa