Full Lyrics
Baba ẹ ṣe p'ore Jesu
Iyin ọpẹ fun Baba
Ẹ lu ago tai tai
Goke tari resimesi
A bi Jesu abo titi
Mẹta juba fun Jesu
Wọle fun 'su Kristi
Maria bi Oluwa gbala ire
Ti de fun wa
Ẹ lu ago ago ago ago ago yọ ayọ
A bi Olugbala
Ni ibuje ẹron
Ilu Bethlehem
Awọn angẹli wọn
Kọrin Hosanna Alleluya
Ẹ wa wo ọmọ tuntun o
Maria bi fun wa
Ogo f'Ọlọrun loke ọrun
Alafiya si ni laye
F'awọn ẹda oninu re
Iranwọ kan lo yọ soju ọrun
Ka lọ juba fun Kabiyesi
Ka lọ wọle fun
Ka f'ori balẹ fun
Ka si ta l'ọrẹ Ọba o
VERSE 2
Awọn angẹli
Oluso mẹta
Kọrin wọn jọ
Juba fun Jesu
Wọn f'oriba
Ṣu wọn f'oriba o
Wọn f'oriba
Ni ibuje ẹron
Imọlẹ ti de
Iranwọ kan yọ o
Awọn angẹli
Kọrin iyin ogo
Imọlẹ de fun wa
A bi Jesu Ọba
Wọn ba wa