Full Lyrics
[CHORUS]
Abẹ o Iya Olugbala
Bẹbẹ fun wa l'ọdọ Ọmọ rẹ
Gbadura fun wa
Iya wa o, bẹbẹ fun wa l'ọdọ Ọmọ rẹ
[VERSE 1]
Iwọ ni'reti wa Maria,
Ayaba Ọrun o
A n bẹ Ọ o b'oju wo wa
Gbadura fun wa
[VERSE 2]
Otosi ẹlẹṣẹ l'awa jẹ o,
Apẹrẹ mimọ ni Maria,
Ẹni ba gbẹkẹle k'o ni padanu
Yio bẹbẹ fun l'ọdọ Jesu Kristi
[VERSE 3]
Ade o, ade o Iya Oluwa
Awa de Iya wa ni oh... awa de
Bẹbẹ fun wa l'ọdọ Ọmọ rẹ