Full Lyrics
[CHORUS]
Abe o, Iya Olugbala,
Bebe fun wa l'odo Omo Re.
Gbadura fun wa Iya wa o,
Bebe fun wa l'odo Omo Re.
[VERSE 1]
Iwo n'ireti wa Maria,
Ayaba Orun o a n be O o
B'oju wo wa o,
Gb'adura fun wa.
[VERSE 2]
Otosi elese l'awa je o,
Apere mimo ni Maria,
Eni ba gbekele k'oni padanu
Yio bebe fun l'odo Jesu Kristi.
[VERSE 3]
Ade o, awa de o
Iya Oluwa awa de
Iya wa ni oh... awa de
Bebe fun wa lodo Omo Re.