Full Lyrics
[INTRO]
Oun gbogbo le le se
Oun gbogbo le le se
Oun gbogbo le le se
[VERSE 1]
Bimo lowo ma fi yin'Oluwa o Lugbala
Oba to da mi
Bimo lowo ma fi yin o Edumare
Dun ni dun ni ninu'ile ogo
[SOPRANO SOLO]
Yungba yungba, kaye ko ye wa
Yungba yungba kaye ko ye wa
Yungba Yungba kaye dara fun wa
[CHORUS]
Yungba yungba kaye yewa kama to si
Dun ni dun ni ninu'ile ogo
Yungba yungba kaye yewa kama to si
Dun ni dun ni ninu'ile ogo
[VERSE 2]
Gbawa lowo ogun esu
Gbawa lowo ogun aye
Kaye mama ridiwa
Kaye ko ye wa o
Kaye ko ye wa o
Obawa ko ye wa wa
Je ka je ere ise owo wa
Ka to pada si O Baba
Dakun o ato farati
Dakun o gbo wa
[OUTRO]
Yungba yungba kaye ko ye wa
Yungba Yungba kaye dara fun wa
Yungba Yungba kaye yewa kama to si
Dun ni dun ni ninu'ile ogo