Full Lyrics
Ṣe ni ma ba Jesu j'ọba
Ṣeni ma d'ade ogo
Ṣeni ma ba Jesu gb'imọ layeraye
Ṣe ni ma ba Jesu j'ọba
Ṣe ni ma tẹju mọ Jesu dandan
Ṣeni ma wa Jesu were
Ṣeni ma ba Jesu l'aja k'aye mi le dara
Ṣe ni ma tẹju mọ Jesu dandan
Ṣe ni ma taku mọ Jesu dandan
Ṣeni ma sunmọ Jesu pẹki
Ṣeni ma ba Jesu l'aja k'aye mi le dara
Ṣe ni ma taku mọ Jesu dandan
Ṣe ni ma ba Jesu kọrin
Ṣeni ma kọrin ogo
Ṣeni ma ba Jesu gb'imọ layeraye
Ṣe ni ma ba Jesu
Kọrin, kọrin, kọrin
Ṣe ni ma ba Jesu kọrin