Full Lyrics
Ounjẹ iye ni! Ara Oluwa ni mo fẹ gba
Ara at'ẹjẹ Rẹ, ni mo fẹ gba.
Ounjẹ iye ni ara Oluwa,
Ara at'ẹjẹ Rẹ, ni mo fẹ gba.
Iwosan ni, Idera de n'ipaṣẹ ara ti mo fẹ gba,
Ara at'ẹjẹ Oluwa, iye ma ni o.
Ara at'ẹjẹ Oluwa, iye ma ni o.
Ounjẹ iye ti o tu mi l'ara,
Ounjẹ iye ti o gba mi la.
Ara at'ẹjẹ Oluwa iye ma ni o.
Ara at'ẹjẹ Oluwa, iye ma ni o.