Full Lyrics
Ounjẹ iye ni! Ara Oluwa ti mo fẹ gba
Ara Kristi at'ẹjẹ Rẹ, ni mo fẹ gba.
Mo ṣe tan o, l'ati jẹ Ounjẹ iye yi
Ara Kristi at'ẹjẹ Rẹ, ni mo fẹ gba.
Igbala ni, Iwosan ni, Idera de
Ni'pa ṣe ara ti mo fẹ gba.
Ara at'ẹjẹ Oluwa, iye ma ni o
Ara at'ẹjẹ Rẹ iye ma ni o.
Ara Oluwa at'ẹjẹ Rẹ
Ounjẹ iye ti o tu mi l'ara,
Ounjẹ iye ti o gba mi la.
Ara at'ẹjẹ Oluwa
Ara at'ẹjẹ Oluwa, iye ma ni o.
Ounjẹ iye o.