OGO NI F'OLORUN by Umeh A. Chinedu Ebiomien & Daniel — Lyrics

Umeh A. Chinedu Ebiomien & Daniel Yoruba Gloria Solfa notation

Full Lyrics

BARITONE SOLO Ògo ni f'Ọlọ́run lókè ọ̀run Àlàáfíà sì ni láyé Fún àwọn ènìyàn onínú rere CHORUS Ará ẹ gbé e ga Ará ẹ gbé e ga Ó rí yẹ ẹ pẹ Ògo yẹ f'Ọlọ́run Ìyìn yẹ f'Ọlọ́run Ògo yẹ, ògo yẹ F'Ọlọ́run wa VERSE 1 Bàbá wa a gbé ọ ga A f'ìyìn àt'ọlá fún ọ Ọlọ́run wa VERSE 2 Olúwa Ọlọ́run wa Ọ̀dọ́ Àgùntàn Ọlọ́run T'ó ńkó ẹ̀ṣẹ̀ ayé lọ Ṣàánú fún wa, gbọ́ tiwa Ògo yẹ f'Ọlọ́run wa VERSE 3 Ìwọ nìkan l'ẹni mímọ́ Olúwa tó ga jùlọ Jésù Ọmọ Bàbá Nínú ìṣọ̀kan Ẹ̀mí Mímọ́ Ògo yẹ f'Ọlọ́run wa

Download the sheet music

OGO NI F'OLORUN

OGO NI F'OLORUN

By Umeh A. Chinedu Ebiomi...
Solfa
Yoruba
1 page
8 Downloads
Gloria
0 0

More lyrics you may want