OGO F'OLORUN L'OKE by Saani Ifeoluwa Richard, S. S. S. Edoki — Lyrics

Saani Ifeoluwa Richard, S. S. S. Edoki Yoruba Gloria Mass Settings Staff & Solfa notation

Full Lyrics

[CHORUS] Ogo ogo f'Olorun l'oke, Ogo ogo f'Olorun l'oke orun. Ogo ogo f'Olorun l'oke, Ogo ogo f'Olorun l'oke orun. [VERSE 1] Ogo f'Olorun l'oke, Alaafia fun eda aye, F'awon eniyan to ni inu rere, Ara e gbega. Anyin ọ, a wole fun ọ, Anyin ọ, awa yin ọ, Awa dupe fun ogo nla re. [VERSE 2] Oluwa Ọlọrun wa, Ọba ọrun, Ọlọrun Baba Olodumare. Oluwa Jesu Kristi, Ọmọ bibi Kansoso, Oluwa Ọlọrun wa, Ọdọ Aguntan Ọlọrun, Iwọ to nko ese aye lọ, Saanu fun wa, Teti siwa. [VERSE 3] O mu ese aye kuro, Baba gbọ adura wa; Iwọ to joko L'ọwọ ọtun Baba, Saanu fun wa. Ko seni Mimọ afi iwọ nikan, Iwọ lo gaju laye. [CODA] At'ọrun, Jesu Kristi Ọmọ Baba, Ninu isọkan Emi Mimọ, Amin.

Download the sheet music

OGO F'OLORUN L'OKE

OGO F'OLORUN L'OKE

By Saani Ifeoluwa Richard...
Staff & Solfa
Yoruba
3 pages
0 Downloads
Gloria Mass Settings
0 0

More lyrics you may want