Full Lyrics
REFRAIN
Ògo ni fun Ọlọrun l'oke Baba Ògo
Ògo f'Ọlọrun l'oke Ọba Ògo
Ògo f'Ọlọrun l'oke... Ògo
Ògo f'Ọlọrun l'oke Ògo
VERSE 1
Ògo ni f'Ọlọrun Baba, Ògo
L'aye alafia f'ẹda, Ògo
To nṣe fẹ Ọlọrun Baba, Ògo
A fi bukun f'Orukọ Rẹ, Ògo
A dupẹ a foribalẹ, Ògo
F'Ọlọrun kan to da awa, Ògo
VERSE 2
Ògo fun Jesu Ọmọ Ọlọrun, Ògo
Kristi Jesu awa sọpẹ, Ògo
Ọdọ agutan Ọmọ Baba, Ògo
To nko gbogbo ẹsẹ ẹda, Ògo
Iwọ nikan lo je mimọ, Ògo
Kristi ẹni to gaju lọ, Ògo
Ọlọrun aye at'ọrun, Ògo
Gbogbo ẹda yio ma yin Ọ, Ògo
VERSE 3
Ẹ wa ka yin Ọlọrun Ẹmi, Ògo
To ba wa gbe titi d'oni, Ògo
Ọlọrun kan pẹlu Baba, Ògo
Ninu Ògo Kristi Jesu, Ògo
Mẹtalọkan awa sọpẹ, Ògo
A fẹ Ọ, awa ma sin Ọ, Ògo
Titi aye gbogbo ẹda, Ògo
Yoo ma kọrin Alleluya, Ògo
Hosanna f'Ọlọrun Ọrun O, Ògo