Full Lyrics
VERSE 1
Nyame Osahen, ama yina koto muo
Meso meko to no bi no mebo nedi da
Nyame, wondi ye me da Enti Ohren
Mebo, mebo wondyan tra man sa
VERSE 2
Jesu l'Oluwa, Ogo Iyin Ola O
Eledumare Baba wa su re fun wa
Jesu, Ogo Ola fun
Oba, awon Oba Ogo iyin ye fun
VERSE 3
Omo Maria, Baba gbogbo araiye
Iwo l'Olugbala Jesu gbo adura wa
Jesu, Omo Maria
Ohun l'Oba awon Oba ogo iyin ye fun
Jesu l'Oluwa