Full Lyrics
Adupe o Baba, Adupe o Jesu.
Adupe o Baba, Adupe o Jesu.
Keresimesi, a wa juba fun o Jesu.
Keresimesi, Keresimesi, Olugbala Kristi ti de.
Ati ri irawo ogo, idunnu si ti kun aye.
Ayo kun orun, a bi Jesu Imanueli.
O awon Angeli n korin ayo, Keresimesi ti de.
Adupe o Baba.
Oba ti de, Olugbala ti de.
Oba ti de, e korin Aleluya.
Alade ogo ti de, e korin Aleluya.
Alade ogo ti de, e korin Aleluya.
Alade ogo ti de.
Ka juba fun Oba, Olugbala ti de.
Ka juba fun Oba, e korin Aleluya.
Ka juba fun Oba, Olugbala ti de.
Ka juba fun Oba, Oba ti de.
Alade ogo ti de, e korin Aleluya.
Wa a nwa, a nwa a nwa,
Emi mimo ni irawo ati,
Rin ati rin ati rin rin rin,
Irawo lo gbe wa de,
A gbagbo ninu Mesaya.
Adari ogo gbe e da,
Nibe tele Emu lati,
Bi Olugbala yi o,
A ti ri irawo re o,
O si n dan yanyan ni.
Ibukun ni fun Maria,
Iya oka igbala,
Ope ope ni fun Josefu,
To duro ti imole e wa,
Nibu gbe eranla.
Ti ri ibi, Keresimesi ti de.
Olugbala wa de,
Irapada a wa ti de,
O se Jesu o, se Jesu.
Oluwa, kaabo o.
Oba ni! Oba ni!