Full Lyrics
REFRAIN
Kabiyesi O Hosanna O
Ẹ yin Jesu Kristi Ọba aiku.
Ẹ gbega, ẹ gbega O, ẹ yin ọm'Ọlọrun
Ẹ yin Jesu Kristi Ọba aiku.
VERSE 1
Wa ka yin Jesu aya mi o
Ọba mimọ Jesu Ọba aiku.
VERSE 2
Wa ka yin Jesu, wa ka yin Jesu
Ẹ gbe ga o, Ọba aiku.
VERSE 3
Wa juba Jesu, ẹ gbe mi o
Yin Eledumare Ọba aiku.
VERSE 4
Obangiji ye o, Oluwa o
Oluwa, wa gbayin awa ọmọ Rẹ,
Wa gbayin awa ọmọ Rẹ.
VERSE 5
Angeli l'ọrun ẹ ba wa yin
Ẹ yin Jesu Kristi Ọba ọrun.
CODA
Kabiyesi O Hosanna O
Ẹ yin Jesu Kristi Ọba aiku.
Ẹ gbe ga, ẹ gbe ga,
Ẹ yin Jesu Kristi Ọba aiku.
Kabiyesi O Hosanna O
Ẹ yin Jesu Kristi Ọba aiku.
Ẹ gbe ga, ẹ gbe ga, ẹ gbe ga, ẹ gbe ga,
Ẹ gbe Jesu ga, ẹ gbe ga Ọba aiku.
HALLELUYA CHORUS
Halleluya si O Oluwa,
Halleluya si O Oluwa,
Halleluya, Halleluya,
Halleluya si Oluwa,
Halleluya si Oluwa.
Ape ọla, iyin f'Olubukun
Adupẹ O, O se Olubukun
Yin f'Olubukun, Hosanna,
Hosanna, Hosanna, Hosanna si Kristi
Ọba iye O, Hosanna, Hosanna, Hosanna,
Hosanna si Kristi Ọba iye O
Hosanna, Hosanna, Hosanna, Hosanna,
Halleluya, Ẹ yin Jesu Kristi Ọba iye o.