Full Lyrics
[SOPRANO]
Ẹrù Ọba ni mo bà, Ọba to
Ẹrù Ọba ni mo bà, Ọba to
Ẹrù Ọba ni mo bà, Ọba to
Ẹrù Ọba ni mo bà, Ọba to
Ẹrù Ọba ni mo bà, Ọba to
Ẹrù Ọba ni mo bà, Ọba to
Ẹrù Ọba ni mo bà, Ọba to
Kabiyesi rẹ o, Ọba to to o Ọba to to o Ọba to to bi aro
Ki le n f'Ọba pe, Ọba o, Ọbalase, Ọba
Ọba o o Ọba t'o w'ẹwu iyi o Ọba yi Ọba o o Ọba
uh uh o Ọba f'Ọba pe e Ọba o f'Ọba pe f'Ọba pe e Ọba.
Ki le n f'Ọba pe e Ọba uh
e Ọba Ọba o o Ọba t'o w'ẹwu iyi o Ọba yi Ọba o o Ọba uh
uh o Ọba Ọba t'o d'ade ọwọ d'ade ọwọ o a d'ade o d'ade o d'ade Ọba
Olori aye
Akọda aye
Atọba j'aye
Ọba to l'aye
Mimọ, Mimọ, Mimọ Mimọ, Mimọ Mimọ Mimọ Mimọ Mimọ Mimọ Mimọ, Mimọ Mimọ, Mimọ Mimọ
[SOPRANO SOLO]
Ẹrù Ọba ni mo bà, Ọba to
Ẹrù Ọba ni mo bà, Ọba to
Ẹrù Ọba ni mo bà, Ọba to
Ẹrù Ọba ni mo bà, Ọba to
Kabiyesi rẹ o
Kabiyesi rẹ o
Kabiyesi rẹ o
Mimọ Kabiyesi rẹ o, Ọba to to o Ọba to to o Ọba to to bi aro
to to to to to to o to to bi aro.