Full Lyrics
[VERSE 1]
Iwo la dahun a ke hun.
Imole yanyan, ina laulau
Okunkun pimpim, Ategun ferefe,
Gbogbo nkan te da o, a wa le fun.
Gbogbo nkan te da o, a wa le fun.
Gbogbo nkan te se, Baba
Gbogbo nkan te se, Baba
Ki la ti ri ki la mo, Baba?
Ki la ti ri ki la mo, Baba?
Eyin l'oba awon oba,
Eyin l'oba awon oba,
[CHORUS]
Alagbara ara! Alagbara ara!
Iba re, Iba re, Iba fun
[VERSE 2]
F'Olu orun
Eh eh eh
Oluwa, e se o! Olorun Oba a dupe o!
Ebun wo lo ju ebun re lo? Ko si! Rara
Afunnimasi regun
Oluwa, e se o! Olorun Oba a dupe o!
Fun ebun idunu to peye, Fun ebun imo ta fi yege
[VERSE 3]
Eh! Eh! Eh! Eh!
Alase aye iba re! Alase orun iba re
Olumorankan iba re
Iba o eh Eh
F'Olu orun
Iba o eh Eh
Eh! Eh! Eh! Eh!
Alase aye iba re! Alase orun iba re
Olumorankan iba re
F'Olu orun
Oo
Iba f'Olu orun
F'Olu orun
Oo
Iba f'Olu orun
Obayeraye, Iba re! Iba re!