Ogo by Okoli Kingsley I — Lyrics

Okoli Kingsley I Yoruba Gloria Solfa notation

Full Lyrics

CHORUS Ogo ni f'Ọlọrun l'oke ọrun Ati alaafia si awọn eniyan rẹ lori ile aye. VERSE 1 Oluwa Ọlọrun, Ọba ọrun, Olodumare ati Baba, A si yan, a dupẹ fun o, A wa yin o o fun ogo rẹ. VERSE 2 Oluwa Jesu Kristi, ọmọ Baba kan soso, Oluwa Ọlọrun, Ọdọ agutan Ọlọrun, Iwọ ni t'onko ẹṣẹ aiye lọ, Gba adura wa. VERSE 3 Iwọ joko lọwọ ọtun Baba, Ṣaanu fun wa. Nitori iwọ nikan ẹni mimọ, Iwọ nikan i Oluwa, Iwọ nikan soso ni ọgaogo julọ, Jesu Kristi pẹlu ẹmi mimọ ninu ogo Baba. AMIN Amin! Amin! Amin o! Amin! Amin! Amin o! Amin! Amin! Amin! Amin o! Amin! Amin! Amin!

Download the sheet music

Ogo

Ogo

By Okoli Kingsley I
Solfa
Yoruba
2 pages
5 Downloads
Gloria
0 0

More lyrics you may want