"GBEBOWA" by Franklin Adidi & Mr John Onasanya — Lyrics

Franklin Adidi & Mr John Onasanya Yoruba Offertory Hymns Hymns Solfa notation

Full Lyrics

CHORUS Gbebọwa, Olodumare gbebọwa Gbebọwa, Olodumare gbebọwa Ẹbọ ta mu wa lati inu ọkan wa Gbebọwa, Olodumare gbebọwa VERSE 1 Akara la mu wa lati fi rubọ si o Oun ni ẹbọ ti awa fi yin o Dakun mase kọ ẹbọ awa ọmọ rẹ Ṣugbọn dakun gbaa bii ẹbọ otitọ Baba VERSE 2 Oti waini la wa fi rubọ si o Oun la mu wa lati wa fi yin o Dakun mase kọ ẹbọ awa ọmọ rẹ Ṣugbọn dakun gbaa bii ẹbọ otitọ Baba VERSE 3 Ọba eti to gbọ ti awa ọmọ rẹ A n sun si o ninu misa oni o Dakun mase kọ ẹbọ awa ọmọ rẹ Ṣugbọn dakun gbaa bii ẹbọ otitọ Baba

Download the sheet music

"GBEBOWA"

"GBEBOWA"

By Franklin Adidi & Mr Jo...
Solfa
Yoruba
2 pages
3 Downloads
Offertory Hymns Hymns
0 0

More lyrics you may want