GBE GÈNGÈ by Ayò Olúrántí — Lyrics

Ayò Olúrántí Yoruba Celebrations Entrance songs Recessional / Dismissal Hymns Anthems Hymns for Saints & Feast Days Staff notation

Full Lyrics

Gbogbo aye gbe Jesu ga, Gbogbo aye gbe Jesu ga, Gbogbo aye gbe Jesu ga, gbe ga, O... Ẹ wọle fun, Ọba awọn Ọba! Ẹ juba fun, Ọba awọn Ọba! Kabiyesi Rẹ Ọba awọn Ọba, Kabiyesi Rẹ Oluwa awọn 'luwa. Ẹ gbe gẹngẹ, Ọmọ Ọlọrun. Ẹ gbe gẹngẹ, Gbongbo idile Jesse. Gbe! gbe! gbe! Gbe ga gbe ga, Gbe! gbe! gbe! Gbe ga gbe ga, gbe gẹngẹ, Ẹ gbe Jesu ga o, Ẹ gbe Jesu, Ẹ gbe Jesu ga o, Ẹ gbe ga o, Oluwa, Olu ọrun ni, Gbogbo aye gbe Jesu ga. Ẹ gbe ga, Gbe ga o, gbe ga o, gbe Jesu ga, Gbe ga gbe ga gbe! gbe! gbe! Gbe ga gbe ga gbe! gbe! gbe! Gbe ga gbe ga gbe! gbe! gbe! Gbe ga! Ẹ wọle fun Ọba awọn Ọba. Ẹ mu ade Ọba Rẹ wa. Ṣe l'Ọba awọn Ọba! Ṣe... Ṣe l'Ọba, Awọn Ọba! Ṣe l'Ọba, Ẹ wọle fun Ọba awọn Ọba. Ẹ mu ade Ọba Rẹ, Gbogbo aye gbe Jesu ga. Gbogbo aye gbe Jesu ga, Gbogbo aye gbe Jesu ga, Ọba aye, Jesu! Ọba ni o, Messiah Jesu l'Ọba, Kabiyesi Kristi Ọba lailai, Messiah, Messiah, Ọba, Irawọ owurọ, Itanna ipado, Messiah, Jesu l'Ọba, Kabiyesi Kristi Ọba lailai. Messiah, Oluwa, Ọlọrun, Messiah, ah, Oluwa, Ọlọrun, gbe ga, gbe ga o. Gbe ga, Gbe ga, Gbe ga, Gbogbo aye, Gbogbo aye, Gbogbo aye, o gbe ga o, gbe ga o, gbe ga o, gbe ga o, Gbe o, gbe ga o, gbe ga o, gbe ga o. O gbe ga o, gbe ga.

Download the sheet music

GBE GÈNGÈ

GBE GÈNGÈ

By Ayò Olúrántí
Staff
Yoruba
13 pages
7 Downloads
Celebrations Entrance songs Recessional / Dismissal Hymns Anthems Hymns for Saints & Feast Days
0 0

More lyrics you may want