Full Lyrics
VERSE 1
Òkùnkùn pim pim, atẹgun fẹrẹfẹ,
Iwọ ladahun akẹhun.
Imọlẹ yanyan, ina laulau
Gbogbo nkan tẹ da o, awa le fun.
Gbogbo nkan tẹ ṣe, awa le ṣe fun baba
Ki lati ri ki la mọ, baba?
Ẹyin l'ọba awọn ọba,
CHORUS
Alagbara ara! Alagbara ara! ẹ!
Iba o! Iba f'Olu ọrun
Iba f'Olu ọrun
Iba f'Olu ọrun
VERSE 2
Afunnimaṣiregun
Iba Iba Oluwa, ẹ ṣe o!
Ọlọrun ọba adupẹ o!
Fun ẹbun idunu to peye,
Fun ẹbun imọ tafi yege
Ẹ bawa gbega o!
Ọlọrun Ọlọrun Ọlọrun Alẹfẹrọpẹdarun.
Ọba titi! Ọba toto
Ọba wa toju igba lailai
Alaṣẹ aye iba rẹ!
Alaṣẹ ọrun iba rẹ!
Olumọrankan iba rẹ
Iba Ọlọrun Ọlọrun Ọlọrun Alẹfẹrọpẹdarun.
CODA
Ọba titi! Ọba toto
Ọba wa toju igba lailai
Alaṣẹ aye iba rẹ!
Alaṣẹ ọrun iba rẹ!
Olumọrankan iba rẹ
Iba Iba!
o! Iba f'Olu ọrun Iba o! Iba
f'Olu ọrun f'Olu ọrun Iba Iba Iba Iba f'Olu ọrun
TENOR SOLO
Ọba ayeraye, iba rẹ! iba rẹ!