Full Lyrics
CHORUS
Babaye, jek'ijoba Re de.
Babaye, jek'ijoba Re bo.
K'ase Re bere l'ori mi,
K'ase Re bere l'aye mi.
CHANTER 1
Baba wa ti n bẹ l'Ọrun, ki a bọwọ fun Orukọ Rẹ;
Ki ijọba Rẹ de, ifẹ tirẹ ni ka ṣe laiye, Bi wọn ti nṣe ni Ọrun;
Fun wa l'onjẹ ojọ wa, Baba wa ti mbẹ l'Ọrun.
CHANTER 2
Dari ẹṣẹ wa ji wa, bi a ti n dari ji ẹnikẹji;
Ma fa wa sinu idanwo laiye, Ṣugbọn gba wa kuro ninu ibi.
CHANTER 3
Nitori ijọba ni tirẹ, Agbara ni tirẹ, Ogo ni tirẹ,
Lai ati lai lai. Amin.