Aderemi D. Olajide YorubaEntrance songsPrayer Solfa notation
Full Lyrics
Baba mimọ a de, awa siwaju rẹ.
Baba mimọ a de, a tun wa juba rẹ,
dari j'ẹsẹ wa ji.
Gba adura wa, Baba.
Ran Ẹmi mimọ rẹ si wa.
Baba mimọ, gbọ adura wa.
Wa f'aṣẹ si, Baba.
Mo f'aṣẹ si, Baba mimọ,
K'adura wa gba l'orukọ Jesu.
Amin o.