Full Lyrics
INTRO
Baba Eledumare,
Ọdọ rẹ lawa wa o
Awa mu ọrẹ wa wa o
Baba wa gbọ'rẹ a wa ọmọ rẹ
CHORUS
Baba Eledumare
Ọdọ rẹ lawa wa
Awa mu ọrẹ wa wa o
Baba, Baba ọrun
Jọwọ gbọ'rẹ a wa ọmọ o
Arinurode olumọran ọkan
Arinurode olumọran ọkan
Wa gba ọpẹ wa
Gbọ'rẹ wa ni ki o fi bukun fun wa o
VERSE 2
Ọba Oluwa ye o
A fa kara rubọ si o
Baba tọwọ gba a
Baba tirẹ niṣe
Sa tirẹ niṣe tọwọ gba a
VERSE 3
Baba mimọ gbọ'rẹ wa gbọ'rẹ wa o
K'ama ṣe padanu Oluwa Jesu
L'aṣẹ rubọ si o Jesu Kristi