Ayọ Igbala by Dotun Olayemi — Lyrics

Dotun Olayemi Yoruba Celebrations Recessional / Dismissal Hymns Anthems Staff notation

Full Lyrics

Ayọ, ayọ, jẹ k'ayọ igbala, Jẹ k'ayọ Baba, jẹ k'ayọ igbala ko tẹle mi. Ayọ, ayọ igbala, ayọ, ayọ igbala, Ayọ, ayọ, ayọ, igbala, Jẹ k'ayọ igbala ko wọnu ọkan mi lọ. Jẹ k'ayọ igbala ko wa wọnu mi. Ayọ, ayọ igbala, ayọ, Ayọ igbala, ayọ, ayọ Jesu, jẹ k'ayọ igbala, Jẹ k'ayọ Baba, jẹ k'ayọ igbala ko wọ 'nu mi. Ayọ, ayọ, ayọ, ayọ Rẹ, Ayọ Baba, ayọ Rẹ. Jẹ k'o wọ wọ 'le mi o, Jẹ k'o la wọ 'le mi o, Owo, ọmọ, pẹl'alafia o Baba, Jẹ k'o wọ wọ 'le mi o, mo wi, Jẹ k'o la wọ 'le mi o, Jesu, Jẹ k'o wọ wọ 'le mi o, Jẹ k'o la wọ 'le mi o, Owo, ọmọ, pẹl'alafia o Baba, Jẹ k'o wọ wọ 'le mi o, mo ma wi, Jẹ k'o la wọ 'le mi o. Ayọ, ayọ igbala, Ayọ, ayọ, ayọ kabiti, Ayọ, ayọ Jesu, jẹ k'ayọ igbala ko, Mo fẹ o Baba ye, mo fẹ rẹpẹtẹ o, Ayọ, ayọ, ayọ, dakun jọwọ, Ayọ, ayọ Baba, Jẹ k'ayọ igbala, Jẹ k'ayọ igbala ko tẹle mi. Dakun jare jaburata Baba ye, Jẹ k'ayọ jaburata ko tẹle mi ṣe, Jẹ k'ayọ itunu ko tẹle mi. Ayọ igbala.

Download the sheet music

Ayọ Igbala

Ayọ Igbala

By Dotun Olayemi
Staff
Yoruba
7 pages
8 Downloads
Celebrations Recessional / Dismissal Hymns Anthems
0 0

More lyrics you may want