Awa Yin O o by Rev. Fr. Martin Badejo — Lyrics

Rev. Fr. Martin Badejo Yoruba Gloria Staff & Solfa notation

Full Lyrics

REFRAIN Awa yin Ọ o, a f'ogo fun Ọ Baba. Ọpẹ yẹ Ọ o, a f'ori balẹ o, Awa yin Ọ o, a f'ori balẹ. VERSE 1 Ogo f'Ọlọrun l'oke, Alafia l'aiye f'awọn oninu rere, Ọla yẹ fun o, ibukun yẹ fun o, Nitori ogo nla rẹ Ọba ogo. VERSE 2 Oluwa Ọlọrun wa o, Ọdọ aguntan t'on ko ẹṣẹ aiye lọ, Ṣaanu fun wa, gbọ adura wa Lat'oke wa o l'ọwọ ọtun Baba. VERSE 3 Iwọ Jesu Kristi, Iwọ nikan ma ni Mimọ o N'inu ogo Ọlọrun t'oga ju lọ Pẹlu Ẹmi Mimọ o Ogo mẹta l'ọkan.

Download the sheet music

Awa Yin O o

Awa Yin O o

By Rev. Fr. Martin Badejo
Staff & Solfa
Yoruba
2 pages
5 Downloads
Gloria
0 0

More lyrics you may want