Full Lyrics
Baba wa a de o. Baba wa a de o.
A de awa yin o, a de o.
Awimayehun! Baba wa a de o.
A de awa yin o, a de o.
Baba fetisi wa
K'oma ta wa danu.
Akigbe si Baba o!
Awa ma de o!
Baba wa dakun,
Baba foriji wa o!
Wa fun wa ni joko.
Awa ma de o!
Baba wa, Oloore, Oluwa
ye jowo o!
Fun wa ni'fokansi.
Awa ma de o!
Baba wa mi si wa!
Oluwa o!
Baba Olodumare!
Awa ma de o!