ARÁMI Ẹ F'ÓGO F'ỌLỌ́RUN. by Ogungbe Femi M — Lyrics

Ogungbe Femi M Yoruba Gloria Mass Settings Hymns Solfa notation

Full Lyrics

INTRO Ara mi ẹ f'ogo f'Ọlọrun Ogo, ogo f'Ọlọrun ọrun loke. REFRAIN Ogo, Ogo f'Ọlọrun ọrun loke. VERSE 1 Alafia fun ẹda aye; F'awọn ẹniyan ti inu rere; Oluwa Ọlọrun awa; Ọdọ aguntan Ọlọrun wa; Ko s'ẹni mimọ afiwọ nikan; Iwọ loga ju l'aye at'ọrun; VERSE 2 Ọlọrun wa a gbe Ọ ga; Iyin atẹwọ f'orukọ rẹ; Iwọ nikan l'O ko ẹṣẹ aye lọ; Ṣaanu fun wa tẹti si wa; Jesu Kristi Ọmọ Ti Baba; Ninu iṣọkan Emi Mimọ o; VERSE 3 Gbogbo ẹda alaye ẹ gbe ga; Gbogbo ẹda alaye ẹ gbe ga; Gbogbo ẹda alaye ẹ gbe ga; Gbogbo ẹda alaye ẹ gbe ga; Gbogbo ẹda alaye ẹ gbe ga; Gbogbo ẹda alaye ẹ gbe ga;

Download the sheet music

ARÁMI Ẹ F'ÓGO F'ỌLỌ́RUN.

ARÁMI Ẹ F'ÓGO F'ỌLỌ́RUN.

By Ogungbe Femi M
Solfa
Yoruba
1 page
8 Downloads
Gloria Mass Settings Hymns
0 0

More lyrics you may want