ARÁ MI Ẹ F'ÓGO F'ỌLỌRUN. by Ogungbe Femi M — Lyrics

Ogungbe Femi M Yoruba Gloria Mass Settings Solfa notation

Full Lyrics

INTRO Ara mi ẹ f'ogo f'Ọlọrun; Ogo f'Ọlọrun l'oke. REFRAIN Ogo, ogo f'Ọlọrun l'oke. VERSE 1 Alaafia f'awọn eniyan to ni inu rere; Ọlọrun wa a gbe ọ ga; Iyin at'ọla f'orukọ rẹ; Gbogbo ẹda alaye ẹ gbe ga; Gbogbo ẹda alaye ẹ gbe ga. VERSE 2 Oluwa Ọlọrun awa; Ọdọ aguntan Ọlọrun wa; Iwọ nikan l'oko ẹṣẹ aye lọ; Ṣaanu fun wa tẹti si wa; Gbogbo ẹda alaye ẹ gbe ga; Gbogbo ẹda alaye ẹ gbe ga. VERSE 3 Ko s'ẹni mimọ afi'wọ nikan; Iwọ l'ọga ju l'aye at'ọrun; Jesu Kristi ọmọ ti Baba; Ninu iṣọkan Ẹmi Mimọ o; Gbogbo ẹda alaye ẹ gbe ga; Gbogbo ẹda alaye ẹ gbe ga.

Download the sheet music

ARÁ MI Ẹ F'ÓGO F'ỌLỌRUN.

ARÁ MI Ẹ F'ÓGO F'ỌLỌRUN.

By Ogungbe Femi M
Solfa
Yoruba
1 page
3 Downloads
Gloria Mass Settings
1 0

More lyrics you may want