Full Lyrics
[INTROSOLO]
Ogo ni f'Ọlọrun loke ọrun,
Alaafia si ni laya f'awọn ẹda Ọlọrun rere.
[VERSE 1]
Baba wa a gbe o ga,
Baba wa a gbe o ga,
Afiyin a t'ọla fun Ọ f'Ọlọrun wa,
Ogo yẹ f'Ọlọrun wa,
Ogo yẹ f'Ọlọrun wa,
Ogo yẹ, Ogo yẹ f'Ọlọrun wa.
[CHORUS]
Ara ẹ gbe e ga,
Ọpẹ yẹ f'Ọlọrun,
Iyin yẹ f'Ọlọrun,
Ogo yẹ f'Ọlọrun wa,
Ogo yẹ, Ogo yẹ f'Ọlọrun wa,
Amin.
[VERSE 2]
Oluwa Ọlọrun wa,
Ọdọ Aguntan Ọlọrun,
Iwọ to nko ẹsẹ aye lọ,
Saanu fun wa gbọ ti wa.
[VERSE 3]
Iwọ nikan l'ẹni mimọ,
Oluwa to ga julọ,
Jesu Ọmọ Baba,
Ninu isọkan Ẹmi mimọ.