GLORIA YORUBA by Jude Nnam — Lyrics

Jude Nnam Yoruba Gloria Mass Settings Solfa notation

Full Lyrics

INTROSOLO Ogo ni f'Olorun loke orun, Alaafia si ni laye f'awon eda ohun rere. VERSE 1 Baba wa a gbe O ga, A f'iyin a t'ola fun O, Ogo ye f'Olorun wa. CHORUS Ara e gbe e ga, Ope ye f'Olorun wa, Iyin ye f'Olorun wa, Ogo ye f'Olorun wa, Ogo ye f'Olorun wa. Amin. VERSE 2 Oluwa Olorun wa, Aguntan Olorun, Iwo to nko ese aye lo, Iwo to nko ese aye lo, Saanu fun wa gbo ti wa. VERSE 3 Iwo nikan l'eni mimo, Oluwa to ga julo, Jesu Omo Baba, Ninu isokan Emi Mimo.

Download the sheet music

GLORIA YORUBA

GLORIA YORUBA

By Jude Nnam
Solfa
Yoruba
3 pages
2 Downloads
Gloria Mass Settings
0 0

More lyrics you may want