Full Lyrics
Alleluya, 'kọrin s'oke.
Alleluya, s'Ọba ọrun.
Abi ọmọ tuntun fun wa,
Ọmọ Maria wundia mimọ.
Tigbo tiju 'gberin ayọ,
k'Alleluya 'kọ gbọrun kọ.
Abi Ọba tuntun fun wa,
Ọmọ Josefu 'gbena 'gbena de.
Alleluya, 'kọrin s'oke,
Alleluia, s'Ọba ọrun.