Yungba K'aiye Ko Yemi by Ike Eseka Esq — Lyrics

Ike Eseka Esq Yoruba Offertory Hymns Celebrations Hymns Prayer Staff & Solfa notation

Full Lyrics

VERSE 1 Bi mo l'owo ma fi yin'Oluwa, Olupese, Baba to dami; Bi mo n'iyi ma fi yin O O'lugbala; Dunmi, dunmi ninu, ye O gbo. VERSE 2 Bi mo l'ola ma fi yin'Oluwa, Olugbala, Baba to funmi; Bi mo l'ola ma fi sin O O Baba; Dunmi, dunmi ninu, ye O gbo. VERSE 3 Bi mo ko'le ma fi yin'Oluwa, Olumoran; Baba to dami; Bi mo l'oro ma fi yin O O Baba; Dunmi, dunmi ninu, ye O gbo. VERSE 4 To mi l'aiye, Baba Olorun, Olugbala; Baba to dami; Funmi l'ayo gan, mo be O O Baba; Dunmi, dunmi ninu, ye O gbo. REFRAIN Yungba, yungba, k'aiye ko yemi; Yungba, yungba, k'aiye dara funmi. Yungba, yungba, k'aiye yemi kin ma m'osi; Dunmi, dunmi ninu ye O gbo.

Download the sheet music

Yungba K'aiye Ko Yemi

Yungba K'aiye Ko Yemi

By Ike Eseka Esq
Staff & Solfa
Yoruba
1 page
9 Downloads
Offertory Hymns Celebrations Hymns Prayer
0 0

More lyrics you may want