YIN OLUWA ỌKAN MI by Benjamin Ogangwu — Lyrics

Benjamin Ogangwu Yoruba Offertory Hymns Hymns Staff & Solfa notation

Full Lyrics

REFRAIN Yin Oluwa ọkan mi, mo fi gbogbo ara yin orukọ mimọ rẹ. VERSE 1 O dari ẹṣẹ ji mi O'nbojuto awọn ailera mi. VERSE 2 Bi mo ba ti sun l'orun O f'angẹli ṣọ mi kin maa sun l'ayọ. VERSE 3 T'aya t'ọmọ awa l'aye O ṣeun, Ọpẹ fun Ọ Baba. VERSE 4 O le, O le, O le iku lọ, O le, O le, O le arun jinna; O sọ, O sọ, imọ ọta d'ofo, wipe, wipe wọn ṣe lasan ni.

Download the sheet music

YIN OLUWA ỌKAN MI

YIN OLUWA ỌKAN MI

By Benjamin Ogangwu
Staff & Solfa
Yoruba
2 pages
11 Downloads
Offertory Hymns Hymns
0 0

More lyrics you may want