Full Lyrics
Yin Oluwa ọkan mi
Mo fi gbogbo ara yin orukọ mimọ rẹ
O dari ẹṣẹ ji mi
O nbojuto awọn ailera mi.
Bi mo ba ti sun l'orun
O f'angẹli ṣọ mi kin maa sun l'ayọ
T'aya t'ọmọ awa l'aye
O ṣeun, opẹ fun O Baba
O lẹ, O lẹ, O lẹ iku lẹ,
O lẹ, O lẹ, O lẹ arun pana,
O sọ, O sọ, imọ ọta dofo,
Wipe, wipe wọn ṣe lasan ni.