Yin Oluwa Okan mi by Ike Al. Eseka — Lyrics

Ike Al. Eseka Yoruba Hymns Offertory Hymns Staff & Solfa notation

Full Lyrics

REFRAIN Yin Oluwa Okan mi, Mo fi gbogbo ara yin oruko mimo re. VERSE 1 O dari ese ji mi, Onbojuto awon ailera mi. VERSE 2 Bi mo ba ti sun l'oru, Onf'angeli so mi kin ma sun l'ayo. VERSE 3 T'aya t'omo awa laaye, Oseun, Ope fun O Baba. VERSE 4 Ko ma sekun pelu ose Ibanuje ko si, ko s'abamo fun mi. VERSE 5 O le, o le, o le iku lo' O le, o le o le arun jina; O so, o so, imo ota d'ofo, Wipe, wipe won se lasan ni.

Download the sheet music

Yin Oluwa Okan mi

Yin Oluwa Okan mi

By Ike Al. Eseka
Staff & Solfa
Yoruba
2 pages
7 Downloads
Hymns Offertory Hymns
0 0

More lyrics you may want