Full Lyrics
[REFRAIN]
Tẹwọ gb'ẹbọ wa,
Baba wa tẹwọ gb'ẹbọ wa,
Baba Olodumare, Iwọ l'a wa rubọ si o.
Tẹwọ gb'ẹbọ wa laye,
Baba wa tẹwọ gb'ẹbọ laye,
Baba wa tẹwọ gb'ẹbọ wa.
[VERSE 1]
Baba Olodumare, Iwọ l'a wa rubọ si o,
Tẹwọ gb'ẹbọ wa.
Awa ẹgbẹ wa paapaa, awọn l'a wa rubọ fun o,
Tẹwọ gb'ẹbọ wa.
Gbogbo Kristiani, awọn l'a wa rubọ fun,
Tẹwọ gb'ẹbọ wa.
[VERSE 2]
Awa pẹlu Maria, Iwọ l'a wa rubọ si o,
Tẹwọ gb'ẹbọ wa.
Awa pẹlu Josẹfu, Iwọ l'a wa rubọ si o,
Tẹwọ gb'ẹbọ wa.
Awa pẹlu Peteru, Iwọ l'a wa rubọ si o,
Tẹwọ gb'ẹbọ wa.
[VERSE 3]
Ko yi pada s'ara Rẹ Jesu,
Oti waini pẹl' akara.
Ko yi pada s'ẹjẹ Rẹ Jesu,
Ko ma yi pada s'ara Rẹ Jesu.