Full Lyrics
Sin wa dele fi isọ rẹ sọ wa,
Oluwa a bẹ jẹ ki ifẹ rẹ tẹle wa, sin wa dele.
Ni itaparo sin wa dele dakun o.
A bẹ ọ, fun wa ni ayọ,
A bẹ ọ, f'abiyẹ rẹ bo wa.
Sin wa dele, wa s'amọna wa.
Ye a bẹbẹ o,
Ninu ewu ba ta nijo isi,
Lọwọ ewu sa bo wa.
Asebi nijo isi,
Lọwọ ewu sa bo wa.
Ore ọfẹ ti Jesu Kristi,
Ati idapọ emi mimọ,
Ko ba wa gbe o, amin asẹ.
Ko ba wa gbe o, amin asẹ o,
Ko ba wa gbe o, amin asẹ.