Șàanu Fún Wá by Odum I. Edward, Nuhu Gabriel, Dofe Michael — Lyrics

Odum I. Edward, Nuhu Gabriel, Dofe Michael Yoruba FILM Songs FILM 2025 Lenten Hymns Communion Hymns Prayer Solfa notation

Full Lyrics

MALE CANTOR(S) Ṣaanu fun wa Ọlọrun Ọba, gẹgẹ bi iṣaro ṣinṣin ifẹ rẹ, gẹgẹ bi ọpọ aanu rẹ, Ki o si pa gbogbo ẹṣẹ wa rẹ. Dariji ẹṣẹ wa jiwa wẹ gbogbo aiṣe dede wa kuro, ki o si wẹ wa mọ kuro ninu ẹṣẹ wa. REFRAIN Ṣaanu, ṣaanu, a'n toro dariji wa. Ṣaanu, ṣaanu, Oluwa o. VERSE TWO Jẹ ki a gbọ ayọ ati inu didun, Jẹ ki gbogbo egun ti iwọ ti rún ki o maayọ. Pa oju rẹ mọ kuro ninu ẹṣẹ wa, Ki o si pa gbogbo àiṣe dèedèe wa rẹ́. TENOR SOLO Da ọkan mimọ sinu wa Ọlọrun, Ki o si tun ẹmi diduro ṣinṣin ṣe sinu wa. Ma ṣe ju wa nu, Ma ṣe ju wa nu kuro ni waju rẹ, Ki o ma ṣe gba ẹmi mimọ rẹ lọwọ wa. CODA Apata ayeraye! Ato farati Ọba! Odo aguntan Ọlọrun Ṣaanu ṣaanu Oluwa o. Ṣaanu ṣaanu Oluwa o.

Download the sheet music

Șàanu Fún Wá

Șàanu Fún Wá

By Odum I. Edward, Nuhu G...
Solfa
Yoruba
3 pages
2 Downloads
FILM Songs FILM 2025 Lenten Hymns Communion Hymns Prayer
0 0

More lyrics you may want