POLONGO JESU by Ayo Ogunranti Jnr — Lyrics

Ayo Ogunranti Jnr Yoruba Folk songs Recessional / Dismissal Hymns Celebrations Concert Solfa notation

Full Lyrics

Jesu ọba ogo, Jesu Ọba ogo o, atẹrẹrẹ kari aye. Atẹrẹrẹ kari aye, atẹrẹrẹ kari aye, o wa sinu ile aye o. Lati wa gba gbogbo ẹda, emi yio pokiki rẹ loke ati ni ile polongo. Polongo, emi yio sọ tẹrẹ ẹ rẹ, emi yio polongo. Polongo o Ọba Jesu polongo, polongo o Ọba Jesu polongo, polongo o polongo o. Polongo o Jesu o Jesu o, polongo Jesu polongo, polongo o polongo o. Polongo o polongo o Ọba Jesu polongo, polongo o Ọba Jesu polongo o Jesu. Polongo o Ọba Jesu polongo o, polongo o polongo ọba polongo o Jesu. O Jesu o o, ẹ polongo, ẹ polongo. O, Jesu ọba ogo, go, Jesu Kristi o. Atẹrẹrẹ kaye ni, atẹrẹrẹ kaye o, polongo Jesu polongo. O, ẹ kọrin ẹ kọrin, emi yio sọ tẹrẹ ẹ rẹ, ẹ jẹ ka sọ to igbala. Polongo Jesu o wa yio polongo Jesu, Jesu Jesu Jesu ẹ jẹ ka polongo o Jesu. Polongo o polongo o, ẹ jẹ ka polongo o, ẹ jẹ ka polongo, ẹ jẹ ka polongo. Ẹ gbe larugẹ, ẹ gbe larugẹ, ẹ gbe larugẹ. Ẹ gbe larugẹ, eṣu koni pamọ, tori mo l'Oluwa. Wa polongo o Baba, eṣu koni pamọ ṣe, tori mo ni Jesu, eṣu ko ni pa o. Tori mo l'Oluwa, tori mo ni Jesu, polongo o Ọba Jesu. Polongo o Jesu o polongo o Ọba Jesu polongo, polongo o polongo o polongo o polongo o. Polongo, polongo, polongo.

Download the sheet music

POLONGO JESU

POLONGO JESU

By Ayo Ogunranti Jnr
Solfa
Yoruba
4 pages
19 Downloads
Folk songs Recessional / Dismissal Hymns Celebrations Concert
0 0

More lyrics you may want