Full Lyrics
CHORUS
Olugbala Jesu Kristi
Mela lokan mi o
Emi mimo o
Amore wa o
Wa gbo ti wa
VERSE 1
Amore wa o
Amore wa o
Baba loke
Oba mimo
VERSE 2
Dariji wa o
Wa dariji wa o
Baba loke
Oba mimo
VERSE 3
E kalle
Alleluia
Alleluia
Oba mimo
VERSE 4
Omo ni yi
Omo ni de
Omo l'ode
O ri eni fun wa ni tawa o
Oba mimo
VERSE 5
T'ebi tara
Je k'ajo yo
Ka jo juba o
F'Oba mimo
VERSE 6
Ilu lo jo ni o
Wa gbo ti wa o
Kawa ma mo si
Si te aiye