Full Lyrics
CHORUS
Olugbala, Jesu Kristi,
mẹta l'ọkan o,
Ẹmi mimọ o,
a mu 'rẹ wa o,
wa gba 'rẹ wa.
VERSE 1
A mu 'rẹ wa o, awa mu 'rẹ wa o,
Baba l'oke,
Ọba mimọ,
a mu 'rẹ wa o,
Ọba mimọ.
VERSE 2
Ọrẹ ni yi, ọrẹ ni yi,
ọrẹ ni yi, fun wa ni ti wa
s'Ọba mimọ,
s'Ọba mimọ.
VERSE 3
Alleluya, alleluya,
alleluya, alleluya,
s'Ọba mimọ,
s'Ọba mimọ.